💬
Home News Ojú Kálé: Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Fi Èrò Wọn Hàn Nípa Ìrànwọ́ Palétíífù...

Ojú Kálé: Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Fi Èrò Wọn Hàn Nípa Ìrànwọ́ Palétíífù Tí Ìjọba Ṣèlérí

Ojú Kálé: Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Fi Èrò Wọn Hàn Nípa Ìrànwọ́ Palétíífù Tí Ìjọba Ṣèlérí
Sponsored Advert
🔴 Breaking News:

Sponsored Ad
Sponsored Ad

A bá àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ nípa ohun tí wọ́n rí sí ìgbésẹ̀ ìjọba àpapọ̀ láti ya owó tí kò dín ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta bílíọ́nù náírà sọ́tọ̀ gẹ́gẹ́ bí Ìrànwọ́ palétíífù fún ará ìlú.

Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló fara mọ́ ìgbésẹ̀ ìjọba yìí, àwọn mìíràn sì dábàá pé kí á padà sí bí a ṣe wà tẹ́lẹ̀, kí ìjọba àpapọ̀ ó dá ìrànwọ́ orí epo padà kí ó lè mú ìdẹkùn bá mẹ̀kúnnù.

[email protected]

Sponsored

Sponsored
Sponsored Ad - Ad Inserter Pro
Top Advert Bottom Advert
Advertisement

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here

© Copyright © 2025 Newspot Nigeria. All rights reserved.
LAGOS WEATHER