💬
Home News Èdè wa ni: Mi o sàdúrà pé kí n ríran mọ́, kí...

Èdè wa ni: Mi o sàdúrà pé kí n ríran mọ́, kí n jéèyàn ló se pàtàkì -Onípènijà ojú

2022: Katsina police kill 54 terrorists  – CP
Sponsored Advert
🔴 Breaking News:

Sponsored Ad
Sponsored Ad

A ṣàwárí àkàndá ẹ̀dá kan tí kò rí òye ayé rí láti ọjọ́ tí wọ́n ti bí i tó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ òfin ni Ifasitì Èkó.

Ó ṣàlàyé bí ìrìn-àjò rẹ̀ ṣe bẹ̀rẹ̀ láti kékeré títí tó fi dàgbà, ó sì gba àwọn ènìyàn tí wọ́n ní ìpènijà ẹ̀ya ara bí i tirẹ̀ nimọ̀ràn lórí bí wọ́n ṣe lè jéèyàn láyé nípa jíjẹ́ akíkanjú àti àìṣe ìmẹ́lẹ́.

[email protected]

Sponsored

Sponsored
Sponsored Ad - Ad Inserter Pro
Top Advert Bottom Advert
Advertisement

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here

© Copyright © 2025 Newspot Nigeria. All rights reserved.
LAGOS WEATHER