Wednesday, January 1, 2025
Home News Okùnfà Aáwọ̀ Láàrin Àwọn Mùsùlùmí Àti Oníṣẹ̀ṣe Ìlú Ìlọrin

Okùnfà Aáwọ̀ Láàrin Àwọn Mùsùlùmí Àti Oníṣẹ̀ṣe Ìlú Ìlọrin

Okùnfà Aáwọ̀ Láàrin Àwọn Mùsùlùmí Àti Oníṣẹ̀ṣe Ìlú Ìlọrin
Advertisement

Ẹ wá wo àkójọpọ̀ fọ́nrán ìbẹ̀rẹ̀ aáwọ̀ tó bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn Mùsùlùmí àti àwọn Oníṣẹ̀ṣe ní ìlú Ìlọrin.

Àwọn Mùsùlùmí fárígá pé kò sí ààyè fún ìbọ̀rìṣà nílú Ìlọrin, àwọn Oníṣẹ̀ṣe náà sì kọtí ikún sí ìdúnkokò àwọn Mùsùlùmí nítorí wọ́n gbà pé àwọn náà ní ẹ̀tọ́ láti ṣẹ̀sìn wọn bó bá ṣe wù wọ́n nílùú Ìlọrin.

Advertisement

Share your story or advertise with us: Whatsapp: +2347068606071 Email: info@newspotng.com


LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here