Ìjà ilẹ̀ pín ẹbí ìdílé ọlọ́ba ìlú ìrayè sí méjì

Ìjà ilẹ̀ pín ẹbí ìdílé ọlọ́ba ìlú ìrayè sí méjì
Advertisement

A ṣe ìrìn-àjò lọ sí ìlú Ìrayè ní ìpínlẹ̀ Ogun níbi tí ìjà ilẹ̀ ti dá gbọ́nmi-sí-i-omi-ò-tó-o sílẹ̀ láàrin àwọn mọ̀lẹ́bi ìdílé ọlọ́ba Ìlú náà tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀mí sì ti bá a lọ.

A bá àwọn ìpín ẹbí méjèèjì sọ̀rọ̀, a sì bá ẹni tí àwọn apá kan talẹ̀ fún, Sir K, sọ̀rọ̀ pẹ̀lú. Gbogbo wọn ni wọ́n ṣe atótónu nípa bí ọ̀rọ̀ náà ṣe jẹ́ pẹ̀lú ẹ̀rí lọ́lọ́.

[email protected]

Share your story or advertise with us: Whatsapp: +2347068606071 Email: info@newspotng.com


LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here