A bá olùsin ajá, Ọlọ́runtọ́ba, sọ̀rọ̀ lórí ìlànà tí ó ń lò láti fi bá àwọn ajá rẹ̀ sọ̀rọ̀ lédè Yorùbá. Ó ṣàlàyé ìfẹ́ tí ó ní sí ajá sínsìn, ó sì gba àwọn ènìyàn níyànjú láti máa fi iṣẹ́ wọn gbé èdè wọn lárugẹ gẹ́gẹ́ bí òun alára tí ṣe.
[email protected]
Share your story or advertise with us: Whatsapp: +2347068606071 Email: info@newspotng.com