Èdè wa ni: Ẹ pàdé Àròjinlẹ̀ tó ń dá àwọn ènìyàn lẹ́kọ̀ọ́ nípa ẹranko lédè Yorùbá

Èdè wa ni: Ẹ pàdé Àròjinlẹ̀ tó ń dá àwọn ènìyàn lẹ́kọ̀ọ́ nípa ẹranko lédè Yorùbá
Advertisement

A bá ògbóntarìgì gbédègbẹyọ tí àwọn èèyàn mọ̀ sí Àròjinlẹ̀ sọ̀rọ̀ nípa àwọn ìwádìí ìjìnlẹ̀ tó máa ń ṣe lórí ẹranko lédè Yorùbá. Ó ṣàlàyé ìdí tí ó fi yan èdè Yorùbá láàyò láti máa fi yànnàná àwọn fídíò rẹ̀ náà.

 

Ó sì gba àwọn òbí níyànjú láti máa kọ́ àwọn ọmọ wọn lédè Yorùbá kí wọ́n má baà kábàámọ̀ láìpẹ́.

[email protected]

Advertisement

Share your story or advertise with us: Whatsapp: +2347068606071 Email: info@newspotng.com


LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here